Song information On this page you can find the lyrics of the song Oré, artist - Aṣa. Album song Beautiful Imperfection, in the genre Иностранная авторская песня
Date of issue: 04.09.2011
Record label: Naïve Records
Song language: Sundanese
Oré |
Ma ya lé mi iwo orè atojubo onilé |
Ma ya lé mi iwo orè agbok’oloko |
Ma ya lé mi awon orè adugbo |
Ma ya lé mi ma ya lé k’omo |
Orè ti mo mu bi aburo |
Orè, orè ti mo sé daara dara |
Orè ti mo fi nu hun |
Owa daami o tumi sita |
Odabi oro ano |
Bi oro ano |
Don’t come to my house |
Iwo orè éké adugbo |
Don’t come to my house |
Iwo orè adaléru |
Maya lé mi, orè kofeniferé |
Maya lé mio maya lé rara |
Isè ni mo wa lojo yi o |
Oko t’o fèmi si lè |
Ko ku lo wa sè sé |
La won mejéji, won bèrè isé kusé |
Won wuma omodé, won sé wun won |
Odabi oro ano |
Bi oro ano |
Ewa wo ija lo jo yen |
Ewa wo éro ton tu ta |
Ewa wo ara lojo yen |
Ejé rée ni le |
Ma ya le mi toro iyo |
Ma ya le mi toro ata |
Ma ya mi le rara |
Isé ku sé kun owo rè |
I don’t want to see you no more |